2. Kro 33:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Manasse mu ki Judah ati awọn ti ngbe Jerusalemu ki o yapa, ati lati ṣe buburu jù awọn orilẹ-ède lọ, awọn ẹniti Oluwa ti parun niwaju awọn ọmọ Israeli.

2. Kro 33

2. Kro 33:3-16