2. Kro 33:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia ilẹ na si pa gbogbo awọn ti o ti di rikiṣi si Amoni, ọba; awọn enia ilẹ na si fi Josiah, ọmọ rẹ̀, jọba ni ipò rẹ̀.

2. Kro 33

2. Kro 33:20-25