2. Kro 32:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tani ninu gbogbo awọn oriṣa orilẹ-ède wọnni, ti awọn baba mi parun tũtu, ti o le gbà enia rẹ̀ lọwọ mi, ti Ọlọrun nyin yio fi le gbà nyin lọwọ mi?

2. Kro 32

2. Kro 32:13-18