2. Kro 32:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LẸHIN ti a ti ṣe iṣẹ wọnyi lotitọ, Sennakeribu, ọba Assiria, de, o si wọ̀ inu Juda lọ, o si dótì awọn ilu olodi, o si rò lati gbà wọn fun ara rẹ̀.

2. Kro 32

2. Kro 32:1-5