2. Kro 31:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu o paṣẹ fun awọn enia ti ngbe Jerusalemu lati fi ipin kan fun awọn alufa ati awọn ọmọ Lefi, ki nwọn ki o le di ofin Oluwa mu ṣinṣin.

2. Kro 31

2. Kro 31:1-9