2. Kro 31:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati fun awọn alufa ti a kọ sinu iwe nipa ile baba wọn, ati awọn ọmọ Lefi, lati ẹni ogun ọdun ati jù bẹ̃ lọ, ninu ilana wọn, nipa ipa wọn:

2. Kro 31

2. Kro 31:16-21