2. Kro 30:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si duro ni ipò wọn, bi ètò wọn gẹgẹ bi ofin Mose, enia Ọlọrun: awọn alufa wọ́n ẹ̀jẹ na, ti nwọn gbà lọwọ awọn ọmọ Lefi.

2. Kro 30

2. Kro 30:7-19