2. Kro 30:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni Judah pẹlu, ọwọ Ọlọrun wà lati fun wọn li ọkàn kan lati pa ofin ọba mọ́ ati ti awọn ijoye, nipa ọ̀rọ Oluwa.

2. Kro 30

2. Kro 30:5-21