2. Kro 29:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si kó awọn arakunrin wọn jọ, nwọn si yà ara wọn si mimọ́, nwọn si wá nipa aṣẹ ọba gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa, lati gbá ile Oluwa mọ́.

2. Kro 29

2. Kro 29:8-25