2. Kro 27:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jotamu si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, nwọn si sìn i ni ilu Dafidi: Ahasi, ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

2. Kro 27

2. Kro 27:8-9