2. Kro 27:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iyokù iṣe Jotamu ati gbogbo ogun rẹ̀, ati ọ̀na rẹ̀, kiyesi i, a kọ wọn sinu iwe awọn ọba Israeli ati Juda.

2. Kro 27

2. Kro 27:1-9