2. Kro 25:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ẹgbãrun alãye li awọn ọmọ Juda kó ni igbekun lọ, nwọn si mu wọn lọ si òke apata na, nwọn si tãri wọn silẹ lati òke apata na, nwọn si fọ́ tũtu.

2. Kro 25

2. Kro 25:9-15