2. Kro 24:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ẸNI ọdun meje ni Joaṣi nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba ogoji ọdun ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ si ni Sibia ti Beer-ṣeba.

2. Joaṣi si ṣe eyiti o tọ li oju Oluwa ni gbogbo ọjọ Jehoiada, alufa.

2. Kro 24