2. Kro 23:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi li ohun ti ẹnyin o ṣe; Idamẹta nyin yio wọle li ọjọ isimi, ninu awọn alufa ati ninu awọn ọmọ Lefi, ti yio ṣe adena iloro;

2. Kro 23

2. Kro 23:2-14