2. Kro 22:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati Ataliah, iya Ahasiah, ri pe ọmọ on kú, o dide o si run gbogbo iru ọmọ ijọba ile Judah.

2. Kro 22

2. Kro 22:1-12