2. Kro 21:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

JEHOṢAFATI si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sìn i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi: Jehoramu ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

2. Kro 21

2. Kro 21:1-5