2. Kro 20:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Juda si kó ara wọn jọ, lati wá iranlọwọ lọwọ Oluwa: pẹlupẹlu nwọn wá lati inu gbogbo ilu Juda lati wá Oluwa,

2. Kro 20

2. Kro 20:1-14