2. Kro 20:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Lefi, ninu awọn ọmọ Kohati ati ninu awọn ọmọ Kori si dide duro, lati fi ohùn rara kọrin iyìn soke si Oluwa Ọlọrun Israeli.

2. Kro 20

2. Kro 20:12-28