2. Kro 20:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo Juda si duro niwaju Oluwa, pẹlu awọn ọmọ wẹrẹ wọn, obinrin wọn, ati ọmọ wọn.

2. Kro 20

2. Kro 20:4-17