2. Kro 20:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O SI ṣe, lẹhin eyi li awọn ọmọ Moabu, ati awọn ọmọ Ammoni, ati ninu awọn ọmọ Edomu pẹlu wọn, gbé ogun tọ Jehoṣafati wá.

2. Kro 20

2. Kro 20:1-11