2. Kro 2:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si yàn ẹgbã marundilogoji ninu wọn lati ru ẹrù, ati ọkẹ mẹrin lati ṣe aké-okuta li ori òke, ati egbejidilogun alabojuto lati kó awọn enia ṣiṣẹ.

2. Kro 2

2. Kro 2:9-18