2. Kro 17:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi ogun sinu gbogbo ilu olodi Juda, o si fi ẹgbẹ-ogun si ilẹ Juda ati sinu ilu Efraimu wọnni, ti Asa baba rẹ̀ ti gbà.

2. Kro 17

2. Kro 17:1-8