2. Kro 17:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi ni iye wọn gẹgẹ bi ile baba wọn: Ninu Juda, awọn olori ẹgbẹgbẹrun; Adna, olori, ati pẹlu rẹ̀, ọkẹ́ mẹ̃dogun alagbara akọni ọkunrin.

2. Kro 17

2. Kro 17:6-18