2. Kro 15:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li ọjọ wọnni alafia kò si fun ẹniti o njade, tabi fun ẹniti nwọle, ṣugbọn ibanujẹ pupọ li o wà lori gbogbo awọn olugbe ilẹ wọnni.

2. Kro 15

2. Kro 15:1-6