2. Kro 13:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li a rẹ̀ awọn ọmọ Israeli silẹ li akoko na, awọn ọmọ Juda si bori nitori ti nwọn gbẹkẹle Oluwa Ọlọrun awọn baba wọn.

2. Kro 13

2. Kro 13:14-21