2. Kro 11:6-9 Yorùbá Bibeli (YCE) O kọ́ Betlehemu pẹlu, ati Etamu, ati Tekoa, Ati Bet-Suri, ati Soko, ati Adullamu, Ati Gati, ati Mareṣa, ati Sifu,