2. Kro 11:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Rehoboamu si ṣe Abijah, ọmọ Maaka, li olori lati ṣe olori ninu awọn arakunrin rẹ̀: nitori ti o rò lati fi i jọba.

2. Kro 11

2. Kro 11:17-23