2. Kro 10:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn o kọ̀ imọran awọn àgbagba ti nwọn ba a dá, o si ba awọn ipẹrẹ ti o dàgba pẹlu rẹ̀ damọran, ti o duro niwaju rẹ̀.

2. Kro 10

2. Kro 10:6-14