2. Kor 9:14-15 Yorùbá Bibeli (YCE)

14. Nigbati awọn tikarawọn pẹlu ẹ̀bẹ nitori nyin nṣafẹri nyin nitori ọpọ ore-ọfẹ Ọlọrun ti mbẹ ninu nyin.

15. Ọpẹ́ ni fun Ọlọrun nitori alailesọ ẹ̀bun rẹ̀.

2. Kor 9