2. Kor 8:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nipa idọgba, pe ki ọpọlọpọ ini nyin li akoko yi le ṣe ẹkún aini wọn, ki ọ̀pọlọpọ ini wọn pẹlu le ṣe ẹkún aini nyin: ki idọgba ki o le wà:

2. Kor 8

2. Kor 8:13-18