2. Kor 7:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi kò sọ eyi lati da nyin lẹbi: nitori mo ti wi ṣãjú pe, ẹnyin wà li ọkàn wa ki a le jumọ kú, ati ki a le jumọ wà lãye.

2. Kor 7

2. Kor 7:1-7