2. Kor 7:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe ibanujẹ ẹni ìwa-bi-Ọlọrun a ma ṣiṣẹ ironupiwada si igbala ti kì mu abamọ wá: ṣugbọn ibanujẹ ti aiye a ma ṣiṣẹ ikú.

2. Kor 7

2. Kor 7:7-15