2. Kor 5:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awa ni ikọ̀ fun Kristi, bi ẹnipe Ọlọrun nti ọdọ wa ṣipẹ fun nyin: awa mbẹ̀ nyin nipò Kristi, ẹ ba Ọlọrun làja.

2. Kor 5

2. Kor 5:11-21