2. Kor 5:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bi awa ti mọ̀ ẹ̀ru Oluwa, awa nyi enia li ọkàn pada; ṣugbọn a nfi wa hàn fun Ọlọrun; mo si gbagbọ́ pe, a si fi wa hàn li ọkàn nyin pẹlu.

2. Kor 5

2. Kor 5:4-13