2. Kor 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa ni iṣura yi ninu ohun èlo amọ̀, ki ọlá nla agbara na ki o le ṣe ti Ọlọrun, ki o má ti ọdọ wa wá.

2. Kor 4

2. Kor 4:1-9