2. Kor 13:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awa nyọ̀, nigbati awa jẹ alailera, ti ẹnyin si jẹ alagbara: eyi li awa si ngbadura fun pẹlu, ani pipe nyin.

2. Kor 13

2. Kor 13:3-14