2. Kor 13:12-14 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Ẹ fi ifẹnukonu mimọ́ kí ara nyin.

13. Gbogbo awọn enia mimọ́ kí nyin.

14. Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa, ati ifẹ Ọlọrun, ati ìdapọ ti Ẹmí Mimọ́, ki o wà pẹlu gbogbo nyin. Amin.

2. Kor 13