2. Kor 11:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe emi njowú lori nyin niti owú ẹni ìwa-bi-Ọlọrun: nitoriti mo ti fi nyin fun ọkọ kan, ki emi ki o le mu nyin wá bi wundia ti o mọ́ sọdọ Kristi.

2. Kor 11

2. Kor 11:1-9