2. Kor 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ireti wa nipa tiyin duro ṣinṣin, awa si mọ̀ pe, bi ẹnyin ti jẹ alabapin ninu ìya, bẹ̃li ẹnyin jẹ ninu itunu na pẹlu.

2. Kor 1

2. Kor 1:1-13