2. Joh 1:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olukuluku ẹniti o ba nru ofin ti kò si duro ninu ẹkọ́ Kristi, kò gba Ọlọrun. Ẹniti o ba duro ninu ẹkọ́, on li o gbà ati Baba ati Ọmọ.

2. Joh 1

2. Joh 1:6-10