2. Joh 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ẹlẹtàn pupọ̀ ti jade wá sinu aiye, awọn ti kò jẹwọ pe Jesu Kristi wá ninu ara. Eyi li ẹlẹtàn ati Aṣodisi Kristi.

2. Joh 1

2. Joh 1:3-13