2. A. Ọba 9:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si debẹ, kiyesi i, awọn olori-ogun wà ni ijoko; on si wipe, Emi ni iṣẹ kan si ọ, balogun. Jehu si wipe, Si tani ninu gbogbo wa? On si wipe, Si ọ, balogun.

2. A. Ọba 9

2. A. Ọba 9:1-7