2. A. Ọba 9:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olùṣọ na si sọ wipe, On tilẹ de ọdọ wọn, kò si tun padà wá mọ: wiwọ́ kẹkẹ́ na si dàbi wiwọ́ kẹkẹ́ Jehu ọmọ Nimṣi; nitori o nwọ́ bọ̀ kikankikan.

2. A. Ọba 9

2. A. Ọba 9:17-29