2. A. Ọba 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ELIṢA woli si pè ọkan ninu awọn ọmọ woli, o si wi fun u pe, Dì amurè ẹ̀gbẹ rẹ, ki o si mu igò ororo yi lọwọ rẹ, ki o si lọ si Ramoti-Gileadi:

2. A. Ọba 9

2. A. Ọba 9:1-7