2. A. Ọba 25:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. O si ṣe li ọdun kẹsan ijọba rẹ̀, li oṣù kẹwa, li ọjọ kẹwa oṣù, ni Nebukadnessari ọba Babeli de, on, ati gbogbo ogun rẹ̀, si Jerusalemu, o si dotì i; nwọn si mọdi tì i yika kiri.

2. A si dotì ilu na titi di ọdun ikọkanla Sedekiah.

2. A. Ọba 25