2. A. Ọba 20:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Kini nwọn ri ni ile rẹ? Hesekiah si dahùn wipe, Gbogbo nkan ti mbẹ ni ile mi ni nwọn ti ri: kò si nkan ninu iṣura mi ti emi kò fi hàn wọn.

2. A. Ọba 20

2. A. Ọba 20:10-19