Ifi 8:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angeli na si mu awo turari na, o si fọ̀n iná ori pẹpẹ kun u, o si dà a sori ilẹ aiye: a si gbọ ohùn, ãra si san, mànamána si kọ, ìṣẹlẹ si ṣẹ̀.

Ifi 8

Ifi 8:2-9