Ifi 7:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si kigbe li ohùn rara, wipe, Igbala ni ti Ọlọrun wa ti o joko lori itẹ́, ati ti Ọdọ-Agutan.

Ifi 7

Ifi 7:2-14