Ifi 4:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa, iwọ li o yẹ lati gbà ogo ati ọlá ati agbara: nitoripe iwọ li o dá ohun gbogbo, ati nitori ifẹ inu rẹ ni nwọn fi wà ti a si dá wọn.

Ifi 4

Ifi 4:4-11