Ifi 2:28-29 Yorùbá Bibeli (YCE) Emi o si fi irawọ owurọ̀ fun u. Ẹniti o ba li eti, ki o gbọ́ ohun ti Ẹmi nsọ fun awọn ijọ.